YO/Prabhupada 0741 - Purpose of Krishna Consciousness movement: Overhauling of the Human Society



Lecture on BG 4.13 -- Bombay, April 2, 1974

Tathā dehāntara-prāptiḥ. Dehino 'smin yathā dehe (BG 2.13). Imoye t'alakoko leleyi, sugbin awon eyan o mo pe ninu ara yi emi wa. Ode ni wan Nitorina lonse juwe wan ninu sastra, sa eva go-kharaḥ: (SB 10.84.13) " Awon eyan wanyi o da ju awon maalu lo." Beena kosi binu yin se fe dun pelu awon eranko. Nitorina ni idaamu se po laarin awon eyan nisin. Kos'aya to da no, teba fe alafia ninu awujo yin, egbodo gba ilana yi. Cātur-varṇyaṁ mayā sṛṣṭam (BG 4.13). awon brahmana gbodo wa, awon ksatriya gbodo wa at awon vaisya. awon ton seto oro aje ni awon vaisya. Rara. Lasiko tawayi awon ton pe vaisya, sudra ni won. awon ton pe ni sudra kere ju sudra lo. Kilode? Nisisn ise vaisya ni kṛṣi-go-rakṣya-vāṇijyaṁ vaiśya-karma svabhāva-jam (BG 18.44). Awon Vaisya gbodo sise pelu ounje, sugbin wan o fe se mo. Wan se da ile ise lati se awon irin ati taya, taya Goodwheel ati Goodyear. Nisisn seyin le je irin ati taywa wan yi. Eyin o le je. Egbodo je iresi, rupees mewa de ni iresi kilo kan. Otan nitoripe kosi vaisya ton gbin ounje mo. ibaje to wa niyen. Sugbin awon eyan yi o le ri. Wan kon paariwo talole gbe iye re soke? Aimoye awon eyan to wa ni Bombay. Melo ninu wan lon gbin ounje? Sugbin woh pe ara won ni vaisya. Iru vaisya wo niyen? Ko s'asa brahmana mo, ko s'opolo mo. Kosi ksatryia mo tole fun yin ni idaabo. Alebu to po gan wa. Teyin ba fe tun ile aye yin se, awujo eda, lori orilede yin tabi lori gbogbo agbaye egbodo gba omiran Krsna Idi fun egbe imoye Krsna yi leleyi: Ke tun gbogbo awujo eyan se. Awon ti da nkankan sile. teyin ba fe je ki ile aye yi niyi, egbodo gba ominiran Bhagavada-gita, t'Olorun so fun ara re, kos'alebu kankan. Tin ba so nkan, alebu le po ninu re, nitoripe mi o je pipe. Gbogbo wa la man se asise. Iwa eda niyen. Koseda kankan tole sowipe " Mio ti se asise kankan." Kolese se. Egbodo s'asise. lehin igba die itanraeni ma wa, pramada. Pe gbogbo wa sin gba ara yi bi wipe " emi ni ara yi". Nkan ton pe ni pramada. Bhrama, pramada. Lehin na vipralipsa. Mito ni bhrama, mon s'asise, mole ni itanra eni Sugbon mo sin rowipe oluko nimi. Itanje niyen. teyin bani alebu to po bayi ninu aye yin, bawo lese le d'Oluko? Oni tanje leyin. Laidi pipe bawo lesele d'Oluko. Nkan ton sele niyen.