YO/Prabhupada 0745 - You Believe or Not Believe, The Words of Krishna Cannot be False



Lecture on SB 7.9.54 -- Vrndavana, April 9, 1976

nisin teyin ba ka gbogbo agbaye, koseni toni gbagbo ninu emi. ko da wonloju pe emi le gba ara imi awon alakowe giga wanyi gan, wan ni gbagbo Beena ele ri fun ara yin bi ile aye yi seri nisin -asiwere nigbogbo wan. asiwere. Otooro gan o le yewonl sugbon wan si pe ara won ni alakowe, onisayensi, oniselu, bayi bayi lo sugbon asiwere ni gbogbo won. Otan. Ipaari oro niyen. Krsna sowipe, dhīras tatra na muhya... Ipaaro ara kan si keji t'emiy Krsna ti salaye pe, dhīras tatra na muhya (BG 2.13)... nkankan na pe, prīṇanti hy atha māṁ dhīrāḥ sarva-bhāvena sādhavaḥ (SB 7.9.54). Teyin o bani oye nipa nkan temi je, nibo ni ibeere nipa ile aye mimo tabi ilosiwaju ninu eto mimo? Kosejo kankan. Ibere ile aye mimo niyen, Ara mi ko nimi. Emi nimi." Ahaṁ brahmāsmi. Koleye won.

Beena tawa ba si gbokan le Krsna.. Agbodo ni gbagbo, ninu oro Krsna. Otooro loje, iro ko. Tein ba je asiwere teyin o fe gba, awon dhira ma gba. Wan ni igbagbo. teyin ba nife Krsna... Koni si'beere ife. Otooro niyen. Ipinnu aye yi niwipem eyan gbodo di dhira, ema huwa ni ologbo ati aja, ton fo kakiri Ile aye eda ko nieyen. Ile aye aja niyen.

yasyātmā-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke
sva-dhīḥ kalatrādiṣu bhauma-ijya-dhīḥ
yat-tīrtha-buddhiḥ salile na karhicit
janeṣu abhijñeṣu sa eva go-kharaḥ
(SB 10.84.13)

awon ipo meta okurin lowa, yasya, "ara mi nimi, Hindu nimi, Musluman nimi, brahmana nimi" Omo ilu India nimi, Omo ilu America nimi... gbogbo aye yi n'ja fun eleyi, nitoripe wanti ya were, dhira ko niwon awujo aye isin. Yasyātma-buddhiḥ kuṇape. ara yi, egungun at'eje nikan lowa ninu e, sugbin wan rowipe ara wan niwon. beena nibo ni agbara ninu ara wa ti wa? Nitoripe lesekese ti agbara yi ba lo, ara yi o le wulo. Seyin rowipe are yi lo fun yin lagbara? Sugbon Dhira koni wa. Asiwere, kole ye won. Oro je pataki gan. Dhīras tatra na muhyati. bawo ni asiwere wanyi fe ni oye na? Nitorina ni egbe imoye Krsna wa sen ko won leeko, otan. Nkan to rorun. At bere lowo wan " Asiwere niyin. Egbiyanju ke ni oye nipa Krsna." Ipenija wa leleyi. E jade wa. Awa ti sowipe asiwere niyin. Egba eko imoye Krsna ki aye yin dara." Imoye Krsna leleyi. Koseni toje dhira.