YO/Prabhupada 1069 - Awon esin aye isin man soro nipa igbagbo. Igbagbo awon eyan le yipo - sugbon Sanatana dharma o le yipo: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1069 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 10: Line 10:
[[Category:Yoruba Language]]
[[Category:Yoruba Language]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1068 - Ise meta lowa fun awon ipo orisirisi iseda aye yi|1068|YO/Prabhupada 1070 - Ise ifarasi Oluwa l'esin tayeraye fun awon eda aye yi|1070}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:

<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|tNIwLyZ9EV0|Religion Conveys the Idea of Faith. Faith May Change - Sanatana-dharma Cannot - Prabhupāda 1069}}
{{youtube_right|tNIwLyZ9EV0|Awon esin aye isin man soro nipa igbagbo. Igbagbo awon eyan le yipo - sugbon Sanatana dharma o le yipo<br />- Prabhupāda 1069}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:660220BG-NEW_YORK_clip13.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660220BG-NEW_YORK_clip13.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 30: Line 33:

<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Nitorina, sanatana-dharma, basele salaaye tele, pe Oluwa ni sanatana, odo metalokan, leyin awon sanmo mimo yi, sanatana na niyen. Awon eda aye yi, sanatana na ni won. Beena pelu asepo laarin Oluwan sanatana, awon eda sanatana, ninu odo metalokan sanatana ni ipinnu aye eda eyan. Oluwa si ni ore-ofe to po gan fun awon eda nitoripe awon dabi omo s'Oluwa. Oluwa gan ti sowipe sarva-yoniṣu kaunteya sambhavanti mūrtayo yāḥ ([[Vanisource:BG 14.4|BG 14.4]]). Gbogbo awon eda.. Awon orisirisi eda lowa pelu karma orisirisi, sugbon Oluwa ti sowipe oun ni baba gbogbo won, beena lati fun won nigbala ni Oluwa sen sokale wa lati mu won pada si sanātana-dhāma, si sanma sanātana, beena awon eda sanatana le beere lati tun ipo sanatana won se ninu asepo pel'Oluwa. Oun gan fun ara re lon wa ninu orisirisi irisi. Nigbami asi ran awon iranse re bi omo re tabi alabasepo tabi acarya lati mu awon eda wanyi pada.  
Ẹsin loye si ero igbagbọ, bẹni igbagbọ si le yipada. eyan le yipo - sugbon Sanatana dharma o le yipo Nitorina, sanatana-dharma, bi a se salaaye tẹle, pe Oluwa jẹ sanatana, ati ibugbe imolẹ, ti o leri isalu ọrun, eyini na jẹ sanatana. Awon eda alaaye, sanatana na ni awon na. apapọ isepọ ti Oluwa Atobiju ati awọn ẹda alãye ni ibugbe sanatana ni asepe ti aye ọmọ eniyan. Oluwa ni oju-anu pupọ fun awọn ẹda alãye nitori wọn jẹ ọmọ Rẹ. Oluwa Ọlọrun kéde ninu Bhagavad Gita sarva-yoniṣu kaunteya sambhavanti mūrtayo yāḥ ([[Vanisource:BG 14.4 (1972)|BG 14.4]]). Gbogbo awon eda.. gbogbo oni ruru awọn ẹda alãye ni wọn wa nibẹ ni ibamu pẹlu orisirisi karmas wọn, sugbọn nibi Oluwa funrarẹ sọ wipe Oun ni baba gbogbo wọn Nitorina ni Oluwa se sọkalẹ lati se irapada gbogbo awọn ti wọn ti kọsẹ wọnyi, awọn ẹmi ninu ide pè wọn pada si ọrun ayeraye sanatana ki awọn ẹda alãye sanatana le ri ipo wọn ayeraye sanatana gba pada ni sepọ pẹlu Oluwa ni aye ainipẹkun. Oluwa nwa funraRẹ ni orisirisi awọn ifarahan bi ẹda, tabi ki o rán awọn iranṣẹ rẹ ti o gbẹkẹle bi ọmọkunrin tabi awọn igba keji Rẹ tabi awọn ācāryas lati se irapada awọn ti wọn wa ninu ide.  

Nitorina sanatana-dharma o kin s'esin fun awon egbe kan soso. Ise tayeraye fun awon eda ninu asepo ton ni pelu Oluwa towa tayeraye. Beena ise tayeraye nitumo sanatana-dharma Śrīpāda Rāmānujācārya ti salaaye nipa oro sanatana " nkan tio n ibeere tabi ipaari." taba de fe soro lori sanatana-dharma agbodo mowipe lori ase Śrīpāda Rāmānujācārya , koni ibeere tab'opin kankan. Oro ton pe l'esin yato si sanatana-dharma. Igbagbo nitumo Esin. Igbagbo yi le yipo. Eyan le ni'gbagbo ninu nkan, toba de ya keyan na si ni igbagbo ninu nkan imi. Sugbon itumo sanatana-dharma ni oun teyin o le yipo. gege bi omi ati sisan. Kosi beyin sele se k'omi ma san. Oru at'ina. Kosi besele yo oru kuro ninu ina. Beena, Ise tayeraye eda ni sanatana-dharma kode si beyin sele yipo. Kosi besele yipo re. Agbodo gbiynaju lati mo nkan toje ise tayeraye fun awon eda. T'a ba n'soro nipa sanatana-dharma agbodo gba wipe lori ase Śrīpāda Rāmānujācārya, koni ibeere ati ipaari. Nkan tio l'opin, ko ni'bere, kode gbodo wa fun esin kan soso. Tawa ban se alapejo lori sanatana-dharma, awon eyan lati awon esin toyato le bere sini rowipe pe awa n'soro lori awon nkan fun esin wa. Sugbon taba wole sinu koko oro, taba si wo gbogbo nkan labe ina sayensi, O daju pe a le ri sanatana-dharma bi'se fun gbogbo awon eda aye yi, rara, gbogbo eda lori agbye yi yi. Awon esin tio mo nipa sanatana, le beere die ninu awujo eda eyan, sugbon kole si itan akoole kankan lori sanatana-dharma nitoripe lati'gba ti aawon eda ti wa loti wa. Beena, lori oro awon eda, a ti ri ninu awon sastra wipe awon eda o le ni iibio tabi iku kankan. Ninu Bhagavad-gita wan ti salaaye wipe awon eda o le ni ibimo, kode si bonsele ku. Tayeraye lo wa fun, asi wa laye leyin igba ti ara eda yi ba tan.  
Nitorina, sanatana-dharma ko se tọka si ilana ẹgbẹ ẹsin kankan. O jẹ iṣẹ ayeraye ti iye ainipẹkun awọn ẹda alãye ni ibasepọ pẹlu Oluwa Atobiju, Ọkan titi aye ainipẹkun. Bi a ti sọ tẹlẹ, sanatana- dharma ntọkasi ojúṣe ayeraye ti awọn ẹda alãye. Śrīpāda Rāmānujācārya ti salaye sanatana funni gẹgẹ bi "eyi ti kò ni ibẹrẹ tabi opin," nitorina nigba ti a ba sọrọ nipa Sanatana-dharma, a gbọdọ gbà bi otitọ lori aṣẹ ti Śrīpāda Rāmānujācārya wipe ko ni ibẹrẹ tabi opin Ẹsin ni ede gẹẹsi yatọ diẹ si itumọ sanatana-dharma. Ẹsin loye si ero igbagbọ, bẹni igbagbọ si le yipada. Eniyan le ni igbagbọ ninu ilana kan pato, àni o si le yi igbagbọ rẹ pada ki o si gba imiran, sugbon sanatana-dharma ntọkasi aṣayan iṣẹ-ṣiṣe eyi ti ko le yipada. Fun apẹẹrẹ, a ko le ya sisan omi kuro lara omi, Oru ati ina. Tabi ki a ya ooru kuro ninu ina. Bakanna, ni a ko le ya iṣẹ ayeraye ti awọn ẹda alãye ainipekun kuro lara wọn. Ko se yipada. A gbọdọ se iwari ipa ti ko le se mani fun ẹda alãye kọọkan. Nigba ti a ba sọrọ nipa sanatana-dharma, nitorina, a gbọdọ gba bi otitọ lori aṣẹ ti Śrīpāda Rāmānujācārya wipe ko ni ibẹrẹ tabi opin. Eyi ti kò ni opin tabi ibẹrẹ kò gbọdọ jẹ iyapa-isin, nitoripe odi kan ko le se lopin. Ti a ba se apejo lori sanatana-dharma, Awọn ti wọn jẹ ọmọ ẹgbẹ ẹsin ẹlẹgbẹ-nsẹgbẹ yoo ṣi ro lasanlasan pe sanatana-dharma na jẹ iyapa-ẹsin. ṣugbọn ti a ba lọ jinna sinu ọran na ki a si ro o loju imọlẹ ti imọ igbalode, o ṣee ṣe fun wa lati ri pe sanatana-dharma ni owo ti gbogbo awọn eniyan araye - rara, ti gbogbo awọn ẹda agbaye. Ẹsin igbagbọ ti kii se sanatana le ni ibẹrẹ ninu ọjọ itan awọn eniyan, ṣugbọn itan sanatana-dharma ko ni ibẹrẹ, nitoripe o ti wa pẹlu awọn ẹda alãye titi ayeraye. Ni eyi ti o fi kan awọn ẹda alãye, awọn iwe mimọ śāstras alasẹ sọ fun wa pe ko si ibimọ tabi iku fun ẹda alãye. O ti wa ni mẹnuba ninu Gita wipe ko si ibimọ fun ẹda alãye bẹni ko si nku. O jẹ ainipẹkun bẹni ko le ni iparun, o si maa tẹsiwaju ninu igbe si aye lẹhin iparun ti ibùgbé awọ ara rẹ.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:30, 14 June 2018

660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Ẹsin loye si ero igbagbọ, bẹni igbagbọ si le yipada. eyan le yipo - sugbon Sanatana dharma o le yipo Nitorina, sanatana-dharma, bi a se salaaye tẹle, pe Oluwa jẹ sanatana, ati ibugbe imolẹ, ti o leri isalu ọrun, eyini na jẹ sanatana. Awon eda alaaye, sanatana na ni awon na. apapọ isepọ ti Oluwa Atobiju ati awọn ẹda alãye ni ibugbe sanatana ni asepe ti aye ọmọ eniyan. Oluwa ni oju-anu pupọ fun awọn ẹda alãye nitori wọn jẹ ọmọ Rẹ. Oluwa Ọlọrun kéde ninu Bhagavad Gita sarva-yoniṣu kaunteya sambhavanti mūrtayo yāḥ (BG 14.4). Gbogbo awon eda.. gbogbo oni ruru awọn ẹda alãye ni wọn wa nibẹ ni ibamu pẹlu orisirisi karmas wọn, sugbọn nibi Oluwa funrarẹ sọ wipe Oun ni baba gbogbo wọn Nitorina ni Oluwa se sọkalẹ lati se irapada gbogbo awọn ti wọn ti kọsẹ wọnyi, awọn ẹmi ninu ide pè wọn pada si ọrun ayeraye sanatana ki awọn ẹda alãye sanatana le ri ipo wọn ayeraye sanatana gba pada ni sepọ pẹlu Oluwa ni aye ainipẹkun. Oluwa nwa funraRẹ ni orisirisi awọn ifarahan bi ẹda, tabi ki o rán awọn iranṣẹ rẹ ti o gbẹkẹle bi ọmọkunrin tabi awọn igba keji Rẹ tabi awọn ācāryas lati se irapada awọn ti wọn wa ninu ide.