YO/Prabhupada 1074 - Gbogbo iyan tan je ninu aye yi - nitori ara eda tani: Difference between revisions
YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0001 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...") |
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists) |
||
Line 1: | Line 1: | ||
<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> | <!-- BEGIN CATEGORY LIST --> | ||
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]] | [[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]] | ||
[[Category:Prabhupada | [[Category:Prabhupada 1074 - in all Languages]] | ||
[[Category:YO-Quotes - 1966]] | [[Category:YO-Quotes - 1966]] | ||
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]] | [[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]] | ||
Line 10: | Line 10: | ||
[[Category:Yoruba Language]] | [[Category:Yoruba Language]] | ||
<!-- END CATEGORY LIST --> | <!-- END CATEGORY LIST --> | ||
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE --> | |||
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1073 - Beena botilejepe awa o le ye ironu lati d'oga iseda aye yi kuro l'okan|1073|YO/Prabhupada 1075 - Awa sin seto ile aye wa to kan ninu aye yi|1075}} | |||
<!-- END NAVIGATION BAR --> | |||
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK--> | <!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK--> | ||
<div class="center"> | <div class="center"> | ||
Line 18: | Line 21: | ||
<!-- BEGIN VIDEO LINK --> | <!-- BEGIN VIDEO LINK --> | ||
{{youtube_right|0hS8FbIU-cY| | {{youtube_right|0hS8FbIU-cY|Gbogbo iyan tan je ninu aye yi - nitori ara eda tani - Prabhupāda 1074}} | ||
<!-- END VIDEO LINK --> | <!-- END VIDEO LINK --> | ||
<!-- BEGIN AUDIO LINK --> | <!-- BEGIN AUDIO LINK --> | ||
<mp3player> | <mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660220BG-NEW_YORK_clip18.mp3</mp3player> | ||
<!-- END AUDIO LINK --> | <!-- END AUDIO LINK --> | ||
Line 30: | Line 33: | ||
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT --> | <!-- BEGIN TRANSLATED TEXT --> | ||
Gbogbo awọn inira ti a ni iriri ni ile aye ni wọn ti inu ara wa, Ibomiiran ninu Gita (8.21) o ti wa bayi pe : | |||
:avyakto 'kṣara ity uktas | :avyakto 'kṣara ity uktas | ||
Line 36: | Line 39: | ||
:yaṁ prāpya na nivartante | :yaṁ prāpya na nivartante | ||
:tad dhāma paramaṁ mama | :tad dhāma paramaṁ mama | ||
:([[Vanisource:BG 8.21|BG 8.21]]) | :([[Vanisource:BG 8.21 (1972)|BG 8.21]]) | ||
Avyakta tumọ si lainifarahan Ani ki ise gbogbo isẹda aye ni o wa ni ifihan niwaju wa. Awọn iye ori wa jẹ aláìpé to bẹ ani a ko ti le ri gbogbo awọn irawọ, gbogbo awọn aye ọrun ti wọn wa ninu agbaye yi. A le ri ọpọ alaye gba ninu awọn iwe Vediki nipa gbogbo awọn aye ọrun, a si le gba wọn gbọ tabi ki a ma fiyesi, gbogbo awọn aye ti wọn jẹ pataki, ni wọn ti wa ni apejuwe ninu awọn iwe Vediki, paapa ninu Śrīmad-Bhāgavatam. Sugbon aye ọrun ẹmí, eyi ti o kọja ode aye yi ([[Vanisource:BG 8.20 (1972)|BG 8.20]]), sugbon avyakta yi, eyini alainifarahan, oun ni paramam gatim, O yẹ ki eniyan nifẹ ki o si lepa ijọba ọrun yi, nitori ti a ba de ijọba ọrun na, yaṁ prāpya, ti oluwarẹ ba sunmọ tabi ti o ba de ijọba ọrun na, na nivartante, ko ni si ipada si ile aye yi mọ. eyini ibi ti o jẹ ibugbe ainipekun Oluwa lati be l'awa o ni lati pada wa.. (isinmi) Nibayi a le se ibeere bawo ni eniyan se le se lati sunmọ ibugbe Oluwa Atobijulọ. Alaye eyi na ti wa ninu Bhagavad-gita. Wọn sọ ni ori iwe kẹjọ, ẹsẹ-iwe 5,6,7,8, ilana lati le sunmọ Oluwa Atobijulọ tabi ibugbe Rẹ na tun ni apejuwe nibẹ. Wọn sọ nibẹ pe: | |||
:anta-kāle ca mām eva | :anta-kāle ca mām eva | ||
Line 44: | Line 47: | ||
:yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ | :yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ | ||
:yāti nāsty atra saṁśayaḥ | :yāti nāsty atra saṁśayaḥ | ||
:([[Vanisource:BG 8.5|BG 8.5]]) | :([[Vanisource:BG 8.5 (1972)|BG 8.5]]) | ||
Anta-kāle, | Anta-kāle, ni opin aye rẹ, lasiko iku. Anta-kāle ca mām eva. Ẹnikẹni na, ti o se ìrántí Krsna, smaran, ti o ba le ranti. Eni ti o nku lọ, lasiko iku, ti o ba se ìrántí irisi Krsna ti o ba fi awọ ara rẹ silẹ ninu ero yi, o daju nigbana o ti sunmọ ijọba Ọlọrun., mad-bhavam. Bhavam tumọ si mimọ. Yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ yāti. Mad-bhāvam ntọkasi titobi ayanmọ Eledumare. Bi a ti sapejuwe tẹlẹ, Ọba Atobijulọ ni sac-cid-ānanda-vigraha (BS 5.1) O ni irisi rẹ, irisi rẹ jẹ ainipẹkun, sat; o kún fun ìmọ, cit; ati alaafia, ananda. Nisin awa gan le yẹ wo ti awọ ara wa yi ba jẹ sac-cid-ānanda. Rara. asat ni ara eda yi. Dipo ko jẹ sat, asat lo jẹ. Antavanta ime dehā ([[Vanisource:BG 2.18 (1972)|BG 2.18]]), Bhagavad-gītā sọ wipe, antavat ni ara ẹda yi, fun igba diẹ lo wa fun. Ati.. Sac-cid-ananda. Dipo kodi sat, o jẹ asat, ilodi lojẹ. dipo ko jẹ cit, kún fun ìmọ, o kún fun aimọkan. A ko ni imọ ti ijọba ọrun, ani a ko ni imọ ni pipe ti aye yi paapaa. ọpọ awọn nkan wa ti wọn jẹ aimọ si wa, nitorina ara yi jẹ alaimọkan. Dipo ko kún fun ìmọ, o jẹ alaimọkan. Awọ ara wa nsègbé, o kún fun aimọkan, ati nirananda. Dipo ki o kún fun alaafia se ni o kún fun inira. Gbogbo awọn inira ti a ni iriri ni ile aye ni wọn ti inu ara wa. | ||
<!-- END TRANSLATED TEXT --> | <!-- END TRANSLATED TEXT --> |
Latest revision as of 00:31, 14 June 2018
660219-20 - Lecture BG Introduction - New York
Gbogbo awọn inira ti a ni iriri ni ile aye ni wọn ti inu ara wa, Ibomiiran ninu Gita (8.21) o ti wa bayi pe :
- avyakto 'kṣara ity uktas
- tam āhuḥ paramāṁ gatim
- yaṁ prāpya na nivartante
- tad dhāma paramaṁ mama
- (BG 8.21)
Avyakta tumọ si lainifarahan Ani ki ise gbogbo isẹda aye ni o wa ni ifihan niwaju wa. Awọn iye ori wa jẹ aláìpé to bẹ ani a ko ti le ri gbogbo awọn irawọ, gbogbo awọn aye ọrun ti wọn wa ninu agbaye yi. A le ri ọpọ alaye gba ninu awọn iwe Vediki nipa gbogbo awọn aye ọrun, a si le gba wọn gbọ tabi ki a ma fiyesi, gbogbo awọn aye ti wọn jẹ pataki, ni wọn ti wa ni apejuwe ninu awọn iwe Vediki, paapa ninu Śrīmad-Bhāgavatam. Sugbon aye ọrun ẹmí, eyi ti o kọja ode aye yi (BG 8.20), sugbon avyakta yi, eyini alainifarahan, oun ni paramam gatim, O yẹ ki eniyan nifẹ ki o si lepa ijọba ọrun yi, nitori ti a ba de ijọba ọrun na, yaṁ prāpya, ti oluwarẹ ba sunmọ tabi ti o ba de ijọba ọrun na, na nivartante, ko ni si ipada si ile aye yi mọ. eyini ibi ti o jẹ ibugbe ainipekun Oluwa lati be l'awa o ni lati pada wa.. (isinmi) Nibayi a le se ibeere bawo ni eniyan se le se lati sunmọ ibugbe Oluwa Atobijulọ. Alaye eyi na ti wa ninu Bhagavad-gita. Wọn sọ ni ori iwe kẹjọ, ẹsẹ-iwe 5,6,7,8, ilana lati le sunmọ Oluwa Atobijulọ tabi ibugbe Rẹ na tun ni apejuwe nibẹ. Wọn sọ nibẹ pe:
- anta-kāle ca mām eva
- smaran muktvā kalevaram
- yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ
- yāti nāsty atra saṁśayaḥ
- (BG 8.5)
Anta-kāle, ni opin aye rẹ, lasiko iku. Anta-kāle ca mām eva. Ẹnikẹni na, ti o se ìrántí Krsna, smaran, ti o ba le ranti. Eni ti o nku lọ, lasiko iku, ti o ba se ìrántí irisi Krsna ti o ba fi awọ ara rẹ silẹ ninu ero yi, o daju nigbana o ti sunmọ ijọba Ọlọrun., mad-bhavam. Bhavam tumọ si mimọ. Yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ yāti. Mad-bhāvam ntọkasi titobi ayanmọ Eledumare. Bi a ti sapejuwe tẹlẹ, Ọba Atobijulọ ni sac-cid-ānanda-vigraha (BS 5.1) O ni irisi rẹ, irisi rẹ jẹ ainipẹkun, sat; o kún fun ìmọ, cit; ati alaafia, ananda. Nisin awa gan le yẹ wo ti awọ ara wa yi ba jẹ sac-cid-ānanda. Rara. asat ni ara eda yi. Dipo ko jẹ sat, asat lo jẹ. Antavanta ime dehā (BG 2.18), Bhagavad-gītā sọ wipe, antavat ni ara ẹda yi, fun igba diẹ lo wa fun. Ati.. Sac-cid-ananda. Dipo kodi sat, o jẹ asat, ilodi lojẹ. dipo ko jẹ cit, kún fun ìmọ, o kún fun aimọkan. A ko ni imọ ti ijọba ọrun, ani a ko ni imọ ni pipe ti aye yi paapaa. ọpọ awọn nkan wa ti wọn jẹ aimọ si wa, nitorina ara yi jẹ alaimọkan. Dipo ko kún fun ìmọ, o jẹ alaimọkan. Awọ ara wa nsègbé, o kún fun aimọkan, ati nirananda. Dipo ki o kún fun alaafia se ni o kún fun inira. Gbogbo awọn inira ti a ni iriri ni ile aye ni wọn ti inu ara wa.