YO/Prabhupada 1062 - Awa sin'iwa lati fe ni idari lori iseda aye yi

Revision as of 09:36, 27 March 2015 by YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1062 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Sugbon asise wa niyen. Nigbat'awa ba ri awon nkan iyanu ton sele ninu iseda aye yi, oye koye wa wipe lehin gbogbo awon nkan wanyi, oludari kan wa. Kosi nkankan tele dasile lai ni idari lori re. Ironu omode loje teyan ba rowipe kos'Olori kankan. gege bi oko to da gan, to yara, pelu erop inu re to da gan, ton saare lopju titi. Omode le ronu wipe "bawo ni oko yi sen sare, laisi esin kankan ton fa?" sugbon eyan toba logbon tabi agba, o mo wipe pelu gbogbo ero towa ninu oko na, laisi oniwako, kosi bosele rin. Ero towa ninu oko, tabi ninu ile-ina monamona.. Nisin lasi asiko tawayi, asik awon ero lawa, sugbon oye ko ye wa pe lehin gbogbo awon ero wanyi, leyin ise nla t'ero yi n'se, oni oniwako to wa n'be. Beena Olorun ni oniwako na, adhyaksa. Oun ni Eledumare labe eni ti gbogbo nkan tin sise. Nisin awon jiva wanyi, tabi awon eda towa laaye, Olorun ti gba won ninu Bhagavad-gita, base ma ri ninu awon apa iwe to kan, pe nkankana lon je pel'Olorun. Mamaivāṁśo jīva-bhūtaḥ (BG 15.7). Apa ati nkankana nitumo Aṁśa. Nisin gege bi iwonba wura die seje wura na, omi iwonba die lat'okun si ni iyo bi omi okun na, beena, awa, awon eda, nkankana laje pel'olori to gaju, īśvara, Bhagavān, tabi Oluwa Śrī Kṛṣṇa, Awa sini, awon iwa Olorun sugbon ni iwonba die. nitoripe isvara kekere niwa, awon isvara kekere. Awa na si fe ni idari lori awon nkan. Awa na fe ni idari lori iseda aye yi. Nisin eyin fe ni idari lori ofurufu. Eyin fe jeki awon isogbe te daa le fo lori ofurufu. Beena iwa lati daa nkan sile tabi lati ni idari lori nkan si wa nitoripe awa na sini awon iwa lati ni idari lori nkan na. Sugbon oye ka mo wipe iwa yi nikan kole to. Awa si ni iwa lati ni idari lori iseda aye yi, lati ni idari lori ile aye yi, sugbon oludari to gaju ko niwa. Beena wanti salaaye ninu Bhagavad-gita.

Lehin na kini ile aye yi? Wanti salaaye nipa re na. Iseda aye yi, wanti salaaye re ninu Bhagavad-gita pe agbara to kere loje, prakrti to kere. Prakrti to kere, ati awon eda si je prakrti to gaju. Oun ton ni idari lori re nitumo Prakrti, Itumo gidi fun prakrti ni obirin tabi abo. Gege bi oko se ni idari lori ise iyawo re, beena, prakrti wa labe idari yi. Olorun, Eledumare, loni idari yi, prakrti yi, awon eda aye yi ati iseda na, prakrti orisirisi lonje, tabi ton wa labe idari Olorun. Beena gege bi Bhagavad-gita se so,, awon eda aye yi, botilejepe nkankana lonje pelu Olorun, prakrti na niwon. Wanti salaaye ninu apa meje ti Bhagavad-gita, apareyam itas tu viddhi aparā (BG 7.5). aparā iyam ni ile aye yi je. Itas tu,prakrti imi si wa na. kini prakrti? Jiva-bhuta,...

Beena prakrti yi, prakrti yi ni amuye meta: ipo rere, ipo ifekeufe, ati ipo aimokan. lori gbogbo awon ipo wanyi, ipo meta orisirisi lowa, rere, ifekufe ati aimokan, asiko tayeraye. Asiko tayeraye. ipaarapo awon ipo iseda wanyi labe idari asiko tayeraye, awon ise wa. Ise, tonpe ni karma. Awon ise tonse lati aimoye asiko awa sin jiya fun tabi awa sin gbadun awon ibajade ise wanyi.