YO/Prabhupada 0091 - Duro sibi nihoho



Morning Walk -- July 16, 1975, San Francisco

Dharmādhyakṣa: Lasiko yi won nmo asise won si gan, won si nkeko iku siwaju sii, ngbiyanju lati je ki awon eniyan mura fun iku die si. Sugbon ohun kan soso ti won le so fun won ni, "E gba be." Ohun kan soso ti won le se ni wipe, "O maa ku. Ki e si gba bee pelu iwa oyaya."

Prabhupāda: Sugbon mi o fe ku. Kilode ti mo se ma ni oyaya? Iwo alaibikita, q so wipe, "e s'oyaya." (Erin) "Soyaya, ka fi e so." (Erin) Agbejoro na a ni, "E ma se yonu. E ti padanu ejo yi. Bayi o le fi idunnu ta'kun." (Erin)

Dharmādhyakṣa: Iyen gangan ni gbogbo ilepa ironuôkàn ode oni. se ni lati mu ki awon eniyan satunse won sinu otito wipe won gbodo duro sinu aye yi. ati wipe ti e ba ni ero lati fi ile aye yi sile, won a so fun yin wipe e ti ya were. "Rara, rara. E gbodo tun satunse die si ipo ti aye yi.

Bahulāśva: Won ko yin lati gba awon ibanuje aye. Won ko yin pe o ye ki e gba gbogbo ibanuje ti aye yi.

Prabhupāda: Kilo nfa ibanuje? E je omowe nla nla. E o le yanju e?

Dharmādhyakṣa: Won o le yanju oro nitoripe awon na ni isoro kan na.

Prabhupāda: Ogbon ironu kanna, "Ko fi oyaya takun." Ko ju yen lo. Ni kete ti isoro die ba ti wa lori koko oro, won a se yonda. Won a si se igbiroigbimo lori ohun ti ko ni laari. Gbogbo e niyen. Eko won ni yi. Eko tumo si atyantika-duḥkha-nivṛtti, igbehin abayo fun gbogbo ibanuje. Iyen ni eko, ki se wipe leyin igbe ti e ba de ipo kan, "Rara, o le ku layo layo. Kini a si npe ni duhkha, ibanuje? Krishna se eyi ni alaaye: janma-mṛtyu-jarā-vyādhi duḥkha-doṣānu... (BG 13.9). Awon ibanuje yin niyi. E gbiyanju lati yanju re. Ati pe won si nyera fun pelepele . Won o le da iku duro, tabi ibi, tabi di darugbo, tabi aarun. Ati fun igba die ti a ma gbe ni aye yi, ibi, ati iku, won nko awon ile nla nla, ti o ba si di igba atunwa ni o ma wa di eku kan ninu awon ile na. (erin) Iseda. E ko le yera fun ofin abayeba. Bi e o se le yera fun iku, bakanna, aseda ma fun yin ni ara miran. Di igi kan ninu ogba Fasiti yi. Duro soke fun egberun odun marun. E fe duro ni ihooho. Nisinyi ko si eni ti o ma lodi si. Duro sibi nihoho.