YO/Prabhupada 0124 - Agbudo mu oro oluko wa gege bi emi ati aye wa

From Vanipedia
Jump to: navigation, search
Go-previous.png Previous Page - Video 0123
Next Page - Video 0125 Go-next.png

We Should Take Up the Words from the Spiritual Master as Our Life and Soul - Prabhupāda 0124


His Divine Grace Srila Bhaktisiddhanta Sarasvati Gosvami Prabhupada's Disappearance Day, Lecture -- Los Angeles, December 9, 1968

akhaṇḍa brahmacārī loje nigba aye re. Omo marun ni Bhaktivinoda Ṭhākura ni, omo karun loun je. Imi ninu awon aburo re Okurin, wan ko lati se igbeyawo. Guru Mahārāja temi na, ko si fe yawo. lati igbato kere brahmacārī to daju ni, Bhaktisiddhānta Sarasvatī Gosvāmī Mahārāja. osini inira topo gan lati bere egbe wa nigbogbo agbaye iṣẹ apinfunni ti Bhaktivinoda Ṭhākura fe niyen. Lati l'odun 1896 ni Bhaktivinoda Ṭhākura tife da egbe imoye Krsna yi sile Osi fiwe yi ranse, Shree Chaitanya Mahāprabhu, Aye ati Eko re. Pelu ore-ofe Kṛṣṇa, odun kanna lon bimi. Nigbato ya asi pade ara wa. Inu ẹbi ton bimisi, yato si ti Guru Mahārāja mi. talomo pe moma bosinu idaabobo re? Talomo pe ma si Orile-ede America? Talomo pe eyin omo-okurin America ma wa ranmilowo? Ise Kṛṣṇa ni gbogbo eleyi. Kole yewa bi awa nkan bayi sen sele.

Ni odun 1936... Ojo kesan Oṣù Ọ̀pẹ̀ , 1938(68). odun mejilelogbon tikoja bayi nigbati mo wa ni Ilu Bombay, nigbayen oni iṣowo timon se. l'ojo kesan tabi ojo kewa l'Osu Ope yi na, nigbayen Guru Mahārāja mi si ni ilera die, nigbaton gbe ni Jagannātha Purī, legbe okun. Mo ko leta si, " Oga mi, awon akeko yin, ati awon brahmacārī, sannyāsī, towa pelu yin gbogbo wan lon sise fun yin. sugbon olori ebi mi nimo je, Mio le wa ba yin gbe, nitorina kosi bimosele sise fun yin. Mio mo. Bawo nimo sele sise funyin?" Mon kan ronu ni, bawo ni mo sele sise fun, " bawo ni mosele sise gidi fun?" Idaaun to funmi wa l'ojo k'etala Osu Ope, l'odun 1936. Ninu leta na osowipe, " Ololufemi, inumi dun gan nigbati mo ri leta re. Mofe ko ti egbe wa siwaju pelu ede geesi". Nkan to ko niyen. "toba lese bayi, ise yi ase gbogbo agbaye ati iwona". O wunmi.... " Ilana to funmi niyen.

Ni Odun 1936, l'ojo mokanlelogbon ni Osu Ope - itumo re niwipe ose meji lehin igbato ko lete yi - Osi fara le. sugbon momu nkan to sofunmi ni pataki, sugbon mio rope mo gbudo se nkanbayi Nigbayen Olori-ile nimo je, sugbon ilana eto Krsna niyen. Tabe gbiyanju lati sise fun Oluko wa, ta se gege bosewi, Krsna na ma funwa nigbogbo nkan tafe. Asiri towa niyen. Nigbayen miori bi mosefe sise na, sugbon momu ise na nipataki mo bere sini ka asọye Viśvanātha Cakravartī Ṭhākura lori Bhagavad-gītā. Ninu iwe Bhagavad-gītā oni ese-iwe to sowipe; vyavasāyātmikā-buddhir ekeha kuru-nandana (BG 2.41), Viśvanātha Cakravartī Ṭhākura si salaaye ese-iwe yi osowipe agbudo mu oro Oluko wa gege bi emi ati aye wa. Agbudo gbiyanju ati tele itọsọna oluko wa, agbudo mu ni pataki lai ronu boya ale jeere tabi aleni ipadanu.

Mosi bere pelu ironu bayi. Osi ti funmi ni gbogbo nkan ti moni lati sise fun. titi de ibi timo wayi, moti darugbo sugbon moti wa si'lu yin, Eyinna tin gbiyanju lati ni oye egbe wa. Atini awon iwe die nisin. Egbe wa tini ipile die. gege na, Ooni je igba kanna ti Oluko mi ti fi ile-aye sile, mosin gbiyanju lati sise re, gege na, Mosi fe ke sise kanna funmi. Agba nimi, mosi le ku nigbakugba. Ofin iseda niyen. Koseni tole daduro. Kosi jamilaya, sugbon ibere mi niwipe nioni ijo kanna bi ijo ti Guru Mahārāja mi ti farale, eyin ti ni oye die nipa egbe imoye Krsna. Egbiynaju ke tesiwaju. Awon eyan jiya nitoripe koseni tole funwan ni imoye yi.