YO/Prabhupada 0174 - Omo-Olorun ni gbogbo awon eda



Lecture on SB 1.8.26 -- Los Angeles, April 18, 1973

Omo-Olorun ni gbogbo eda je . Baba to gaju ni Olorun je siwa. Kṛṣṇa says: ahaṁ bīja-pradaḥ pitā. "Emi ni baba gbogbo eda agbaye." Sarva-yoniṣu kaunteya (BG 14.4). Ibikibi ton ba wa, eda nigbogbo wan je, omo lon je simi." Otito loje. Eda ni gbogbo wa je, omo-Olorun sini wa. Sugbon a ti gbagbe. Nitorina lasen ja. gege bi ile to dara, ti awon ba mowipe: " Baba wa lon pese ounje funwa, aburo laje si ara wa, kilod ta sen ja?" Gege na tabe ni imoye Olorun, taba ni imoye Krsna gbogbo ija yi ma tan. " Omo- ilu America nimi, Omo-ilu India nimi, Omo-ilu Russia nimi, Omo-ilu China nimi." Gbogbo iranu yi ma tan. Egbe imoye Krsna yi si da gan. Lesekese ti awa eyan bba ni imoye Krsna, gbogbo awon ija yi, awon ija eto iselu, awon ogun orile-ede, gbogbo e loma tan lesekese. Nitoripe wan ma mowipe Olorun ni oludari gbogbo nkan. awon omo le gba ounkoun tonba fe lowo baba wan, gege na ti gbogbo wa ba je nkankanna pelu Olorun, omo-Olorun la je nigbana, gbogbo wa lale lo nkan baba wa. awon eda le se bayi. gege bi iwe Bhagavad-gita, awon eda aye yi lole se bayi. Ema ronu boya eda eyan loje, tabi eranko, tabi igi, tabi eye tabi kokoro. Imoye Krsna leleyi. Awa o de gbudo ronu wipe aburo mi nikan loda tabi emini kan leni toda. Gbogbo awon iyoku o da. Iru ironu bayi o da, agbudo ti si ta. Oye ka ronu wipe: paṇḍitāḥ sama-darśinaḥ (BG 5.18). Ninu iwe Bhagavad-gītā ele riwipe.

vidyā-vinaya-sampanne
brāhmaṇe gavi hastini
śuni caiva śva-pāke ca
paṇḍitāḥ sama-darśinaḥ
(BG 5.18)

Eni to ba je paṇḍita, oju kanna lo fin wo gbogbo awon eda. Nitorina ni awon Vaisnava se l'aanu. Lokānāṁ hita-kāriṇau. Wanle sise apinifunni fun gbogbo agbaye. Wanti riwipe gbogbo awon eda wanyi, wan s'arapo pelu Olorun. Sugbon bakanna wanti bosinu ile-aye yi, wande tigba orisirisi ara bi iru karma ton ni. Gege na awon pandita, ton keko, wan o kin se idayato pe: "Eranko leleyi agbudo gbe lo si ile-iperan ka pa dannu, tabi Okurin leleyi oun loma je wan." rara. Eyan toba ni imoye Krsna o si l'aanu si gbogbo awon eyan. Kilode tefe mu awon eranko yi losi ile-iperan. Nitorina imoye wa niwipe awa o gbudo jeran. Ema jeran. Eyin o gbudo se. Sugbon awon eyan yi o ni go. " Oh, iru iranu wo leleyi? Ounje wa leleyi. Kilode teyin ofe ka jeun?" Nitoripe edhamāna-madaḥ (SB 1.8.26). Asiwere toti moti yo loje. Kosi bosele gbo oro gidi.