YO/Prabhupada 0226 - Iwaasu nipa Oruko, ogo, ise, ilewa ati ife Olorun



Lecture -- Los Angeles, May 18, 1972

Ni ooto, Krsna o si ninu aye yi Gege bi eyan pataki, ile-ise re sin lo boseye, sugbon kno se dondon pe o gbudo wan be gege na agbara Krsna s'ise. Awon Iranlọwọ re na sin s'ise. wan si juwe wan ninu śāstra. gee bi oorun Oorun je idi ti gbogbo agbaye si wa laye, iwe Brahma-saṁhitā si wi be.

yac-cakṣur eṣa savitā sakala-grahāṇāṁ
rājā samasta-sura-mūrtir aśeṣa-tejāḥ
yasyājñayā brahmati sambhṛta-kāla-cakro
govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi

Oorun je Ikan ni awan oju Olorun, Ko si nkan ti Olorun o leri Eyan o le sapamo si Olorun, gege bi a se le sa pa mo si Oorun gege na Olorun le ni orisirisi oruko Awon iwe mimo Veda si so wi pe Olorun ni Oruko to po Sugbon Oruko re "Krsna" si ni eyi to ga ju ninu gbogbo oruko re Itumo Mukya ni t'alakoko. Wan si ju we re dada: " arẹwa Oluwa si rewa Egbe imo-oye Krsna sin gbiyanju lati se iwaasu oruko Olorun Ogo Oluwa, Ise Oluwa, Arewa Oluwa, Ife Oluwa, gbogbo nkan. gege ba se ni orisirisi nkan laaye yi, be na ni gbogbo wan awa ninu Krsna Ohunkohun te ba ni.

Gege bi aye ta wa, nkan to se pataki ju ni imọ akọ tabi abo. iyen na si wa ninu Krsna. Awa sin sadura fun Rādhā ati Kṛṣṇa Sugbon ifanimora teyi yato si t'aye ta wa. T'Oluwa se gidi, sugbon t'awa yato awa na sin s'eto gbogbo nkan to wa ni ile-Oluwa sugbon tiwa wòye t'oluwa. Tiwa O ni yi gege bi ile-ise aranṣọ, eyan le ri awon ọmọlangidi to rewa obirin to rewa sin duro sugbon ko seni ton wo Nitoripe gbogbo eyan mo pe kon se gidi ko si bo se le rewa to, gbogbo eyan mo pe, gidi ko. sugon obirin to je eyan, to ba rewa awon a si ma wo nitoripe eyi je gidi. Ninu aye yi na, nitoripe ati iyepe ni ara ti wa , awa na jo awon ere ni ile-ise aranso lesekese ti emi ninu obirin to rewa ba kuro, koseni to fe wo mo nitoripe o si jo ere ni ile-ise aranso gege na nkan to se pataki ni emi to wa ninu gbogbo wa nitorina ara ta ni yi ifirawe lo je Nkan to se pataki ni odo-metalokan.

Awon ton ti ka iwe mimo Bhagavad-gītā om ye wan. Wan si juwe bi ile-oluwa se ri paras tasmāt tu bhāvo 'nyo 'vyakto 'vyaktāt sanātanaḥ (BG 8.20). Itumo Bhāvaḥ ni ayanmọ Osi ni ayanmọ mi to ko ja ti ile-aye yi. Asi le ri pe ayanmọ ti aye yi, lori ofurufu lo tan si awon oni sayensi fe lo si isọgbe-oorun to ga ju, sugbon wan so wi pe o ma to Ẹgbaaji lona mewa odun ton ma fi de be Ta lo le gbe ninu aye fun odun Ẹgbaaji lona mewa. gege na awa o si le siro gigun ati giga ile aye yi, ka ma wa so ti Oorun. Nitorina agbudo fe eit si fun awon olori. Olori giga ni Krsna nitoripe asi ti mo pe ko seni to gbon ju Krsna lo Krsna si ti fun wa l'ogbon, paras tasmāt tu bhāvo 'nyo (BG 8.20). Lehin ile-aye yi o si ni aye mi ni oorun. awon isọgbe-oorun si po nibe Ofurufu ti awna so yi o si tobi ju ti aye yi lo gan ikan ninu merin ni aye yi je, Oorun je meta ninu merin iwe imo Bhagavad-gītā si juwe gbogbo eleyi na Meta ninu merin ni OOrun je Ka so wipe gbogbo araye ti Olorun da pe Ogorun lo je, medogbon ni ile-aye yi, marundilogorin to ku Oorun ni ye je Gege na, awon eda to wan ninu aye yi, wan si kere gan sugbon opolopo ninu wan wa ni oorun.