YO/Prabhupada 0227 - Kini idi fun iku mi



Lecture -- Los Angeles, May 18, 1972

Lati ni Oye Krsna ko fi be rorun gege na, lati ni oye Olorun kon seto to rorun Sugbon Oluwa si ti saalaye ara re ni iwe mimo Bhagavad-gītā. " bi mo se je ni, bi ile-aye se ji ni, bi awon eda se je ni" Wan si ti saalaye gbogbo nkan ninu iwe Bhagavad-gītā. Oluwa fun ara re si fun wa ni oye ma sele le mo, ilana sos to wa lati mo Olorun ni ye Bibeko, awa o si le mo Oluwa ta ba fe fi ori wa ro Ko le se se. Alaini Opin l'Oluwa je, sugbon awa si ni Opin Imo oye wa, ati iwoye wa gbogbo e lo ni Opin Bawo la se le ni oye Alainiopin? Sugbon ti awa b a si gba nkan ti alainiopin ba so, pe bi oun se je ni, igbayen ni kan lale mo Imo ohun gidi ni yen je. Imo ohun ti o ni di nipa Oluwa ko si ni yi. fun apẹẹrẹ Ti omode ba fe mo baba re, nkan to ye to ko se ni lati beere lowo iya re tabi ki iya re so wi pe," Wo baba re". Imo ohun to da ni yen Sugbon te ba fe fori wo, "tani baba mi", ke si ma beere lowo gbogbo eyan", Se eyin ni baba mi? Ko si bo se le mo eyan to je baba re gege na to si gba ilana to rorun, to bi iya re nipa eni to je baba re Iya re a si so fu " Omo mi wo baba re ni bi". Imo oye to dara ni eyi je.

Gege bi mon sen so tele pe Oorun si wa. Kon se nkan afori wo Sugbon ti Olorun ba so wi pe Oorun be, ibi ti mo de wa ni yen. Agbudo gba be Lati Olorun fun ara re ni awan gba imoye. Oun ni Olori giga Nitorina Imoye wa si daju. Awa o le so wi pe a daju, sugbon imoye ta ni daju Nitoripe at'Oluwa lati gba imoye na gege bi apeere ti mo fun yin ni pa eni to fe mo baba re sugbon iya mi daju pe eyan bayi ni baba mi, nitorina mo si gba imoye mama mi nitoripe o daju Gege na a ti da egbe imoye Krsna yi lati fun awon eyan ni imoye to daju Eni ti Oluwa je, kini ile-aye yi, kilode te fi wa si bi? kilode ti ile-aye yi se i'isoro bayi? kilode ti awon man ku? Mi o fe ku sugbon dandan ni iku je Mi o fe darugbo, sugbon dan dan ni Mi o fe ni aisan, sugbon dan dan ni Agbudo yanju gbogbo awan nkan yi.

Awon isoro aye kon se pe ka ma seto ba se ma jeun, mu, sun, at se asepo. Ile aye eda ko ni ye je Awon aja man sun gege bi eyan na Nitoripe awon eyan man sun ninu yara to da eyin ko lo se pe ada ju awn aja lo awon meejeji sun otan Nitoripe awon eyan lo ohun-ìjàohun-ogunohun ílò ati pe awan aja sin lo ekan ati eyin Sugbon o si le ja.. Eyan o le so wi pe nitorip e mo ni ohun-ìjàohun-ogunohun ílò yi mo le gba ijoba gbogob aye ko le se se. gege bi eyin sen ja, gege na ni aja na sen ja ni iwonba tie gege na pe eyin jeun bi olori, tabi eyin sun bi olori tabi eyin se asepo t'oko ti iyawo bi olori, gbogbo eleyi o le fun yin ni ilosiwaju Ilosiwaju ko ni yen. Nkankanna ni ni iwonba to ye, marun lori egberun meji, tabi ogorun marun lori egberun meji.. Nitorina, pe awon eyan seto awon eranko iyen so wi pe ati ni ilosiwaju Ile-aye eranko lo si je. Otan Ilosiwaju gidi ni imo Olorun. Ilosiwaju to da ni yen.