YO/Prabhupada 0385 - The Purport to Gauranga Bolite Habe



Purport to Gauranga Bolite Habe -- Los Angeles, December 29, 1968

Narottama dāsa Ṭhākura lo korin yi, olufokansin ti acarya giga ninu esin Gaudiya Vaisnava Sampradaya. Itumo Gauḍīya Vaiṣṇava Sampradāya ni awon olufokasin ton tele ilana lati Oluwa Caitanya. Beena Narottama dasa Thakura ti ko won orin to po, awon Vaisnava si da awon orin re mo. O ti ko awon orin yi ni ede Bengali to rorun, sugbon itunmo awon orin yi se pataki gan. O sowipe: gaurāṅga bolite habe pulaka-śarīra. Ipo to gaju ninu orin kiko leleyi, pe lesekese taba korin tabi ta mu oruko Oluwa Gauranga, to da egbe Sankirtana, lesekese ti ara re ma bere sini gbon. Kon se nkan toyeka farawe. Sugbon Narottama dasa Thakura ti salaaye wipe ti asiko na bade funwa, ara wa na mabere sini gbon taban korin oruko Gauranga. lehin gbigbon yi, hari hari bolite nayane ba'be nīr, omi ekun ma wa loju wa taba si Korin Hare Krsna yi tan. Lehin na o sowipe, āra kabe nitāicand koruṇā karibe. Gbogbo wa lan bere funn ore-ofe Oluwa Nityananda. Nityananda ni oluko mimo gbogbo wa. Pelu ore-ofe Oluwa Nityananda lale sunmo Gauranga, tabi Oluwa Caiitanya. Kini awon aami idayato tale fi mo awon eyan tonti gba ore-ofe Oluwa Nityananda? Narottama dāsa Ṭhākura sowipe eyan toti gba ore-ofe Oluwa Nityananda yi, kole ni awon ifekufe okan mo. Aami idayato to wa niyen. Āra kabe nitāicand koruṇā karibe saṁsāra-vāsanā mora kabe tuccha. ife fun igbadun aye yi nitumo Saṁsāra-vāsanā, nigbawo loma di nkan pataki. agbudo gba orisirisi nkan nitoripe awa ni ara eda yi. sugbon konse fun igbadun, sugbon fun itoju ara at'emi wa. o si sowipe. rūpa-raghuṇatha-pade haibe ākuti. Nigbawo ni mole ni anfaani lati ka awon iwe Goswami mefa. Anfaani nitumo Akuti.

Ikan.... Nitoripe Rupa Gosvami ni baba ise ifarafun Oluwa. Oun lo kko iwe, Bhakti-rasāmṛta-sindhu. ninu iwe na wansi juwe dada. Ni otitooro, ninu Caitanya-caritāmṛta, ati awon iwe imi... Ati fun yin lenu kan, gbogbo awon eto yi ninu awon iwe wa, Eko Oluwa Caitanya. Agbudo ko nipa eto ife ti Radha-Krsna, lati awon eko Gosvami mefa. Narottama dāsa Ṭhākurati salaaye wipe ema gbiyanju lati mo nipa ife Radha-Krsna pelu ogbon ori lasan. E gbodo gbiyanju lati mo pelu ijuwe awon Gosvami Beena Narottama dāsa Ṭhākura ti korin...(Isinmi) ...Narottama.

rūpa-raghunātha-pade haibe ākuti
kabe hāma bujhaba śrī yugala-pīriti

Ife ajosepo nitumo Yugala-pīriti. Nibomi otun korin pe viṣaya chāḍiyā kabe śuddha ha'be mana. Okan wa, otipe toti wa ninu awon ironu aye yi, kole wonu ijoba Vrndavana. Narottama dāsa Ṭhākura says: viṣaya śuddha kabe śuddha ha'be mana. Okan mi a yasi mimo, tosi nigbala lati awon isoro ati ifekufe okan, lehin na mole ni oye nipa nkan ti Vrndavana je, nkan ti ife Radha ati Krsna yi je, lehin na ile aye mi a ni ilosiwaju.