YO/Prabhupada 0386 - The Purport to Gaurangera Duti Pada



Purport to Bhajahu Re Mana -- The Cooperation of Our Mind

Yāra dhana sampada, sei jāne bhakati-rasa-sāra. orin imi ti Narottama das Ṭhākura ko leleyi, o sowipe " Eni toti gba idaabo labe ese Oluwa Caitanya, beena eni toje pe, gbogbo ohun ni re ni awon ese meji ti Oluwa Caitanya, eyan bayi le mo nipa koko eto ise ifarasi Oluwa." Sei jāne bhakati-rasa-sāra. koko eto ise ifarasi Olorun,ati nkan idunnu towa ninu ise ifarafun Olorun, eyan toti gba idaabo labe ese Oluwa caitanya bi gbogbo nkan toni nikan lole ni oye nipa eto yi. koko oro to wa niwipe, Krsna ni Oluwa Caitanya je, O sin ko awon eda fun ara re, nipa ise ifarafun Oluwa. Nitorina awon ipo ise ifarafun ti Oluwa Caitanya ko wa lo gaju. kosi iyemeji kankan. Olori lon ko iranse lati sise na. Teyan ba je olori ise ero, tabi ile-ise ton ko awon omo ise re fun ara re, ikeko yi lo daju. Beena, Oluwa Krsna fun ara re, to wa bi olufokansi, lon ko wa nipa ise ifarasi Olorun. Nitorina ona ti Oluwa Krsna ti fihan wa lo daju fun ise ifarafun Oluwa. Sei jāne bhakati rasa sāra. koko oro nitumo Sāra. Lehin na o sowipe, gaurāṅgera madhuri-līlā, yāra karṇe praveśilā. Nisin O salaaye nipa awon itan idaray ti Oluwa Caitanya. O sowipe " Awon itan idaraya ti Oluwa Caitanya si ni ipo giga kanna bi t'Oluwa Krsna." Bi Bhagavad-gita se so enikeni toba le ni oye, nipa ifarahan mimo, ipaare, ise ti Krsna, lesekese loma ye ni yiyan lati pada si ile, pada si odo Metalokan. Beena pelu oye nipa awon itan idaraya ati ise Krsna. Beena, enikeni to ba wonu itan idaraya Oluwa Caitanya, lesekese loma nigbala lati awon idoti okan re.

Gaurāṅgera madhuri-līlā, yāra karṇe praveśilā. Itumo Karṇe praveśilā niwipe agbudo gba oro Oluwa Caitanya. Inu eti nitumo Karṇe. Lati ni igboran si oro to muwa. Lehin na lesekese ni okan wa ma bo lowo awon idoti aye yi. Lehin na osowipe: yei gaurāṅgera nāma laya, tāra haya premodaya. Awon elesin fe mo bonsele ni ife to po fun Olorun. Narottama dāsa Ṭhākura sowipe enikeni tofe korin, śrī-kṛṣṇa-caitanya prabhu-nityānanda...Pelu gbogbo awon ohun ise re nitumo Gaurāṅga Lesekese taba soro nipa gauranga, awa n'soro nipa awon marun: Oluwa Nityananda, Advaita, Gadadhara ati Srivasa. Gbogbo wan papo.

Beena yei gaurāṅgera nāma laya, enikeni toba korin, lesekese loma ni ife fun odo metalokan. Yei gaurāṅgera nāma laya, tara haya premodaya, tāre mui jaya bole hari. Narottama dāsa Ṭhākura sowipe, " Moki lo riire." Nitoripe o daju pe oti ni ife si odo Metalokan. lehin na, gaurāṅga-guṇete jhure, nitya-līlā tāre sphure. Enikeni, toba l'anfanni, lati gbo nipa awon amuye Caitanya Mahaprabhu, lesekese loma ni oye nipa awon eto ife laarin Radha ati Krsna. Itan idaraya nitumo Nitya-līlā, tabi awon itan idaraya laarin Radha ati Krsna. Nkan t'ayeraye Fun igba die lowa fun. Awa o gbodo rowipe awon itan idaraya Rādhā-Kṛṣṇa, awon ibasepo ife, dabi awon ife laarin okurin ati obirin lasan, ninu aye yi. Ifekufe aye yi o kin se ife gidi Ifekufe lasan lonje, fun igba die lonwa. Nitorina lonse tan Moni ife eyan leni, lojokeji ife na ti tan. Sugbon Rādhā-Kṛṣṇa līlā o kin se bayi. Nkan aye raye. Nitorina oun lo gaju, fun igba die ni taye yi je. beena enikeni toba wa ninu itan idaraya Oluwa Caitanya, lesekse loma ni oye nipa oye oye ife Radha-Krsna. Nitya-līlā tāre sphure. Sei yaya rādhā-mādhava, sei yaya vrajendra-suta pāśa. toba si fe, o le wonu odo metalokan ti Krsna. Vrajendra-suta. Omo Nanda Maharaja nitumo Vrajendra-suta ni Vrndavana. O daju pe ni aye tokan eyan bayi ani asepo pelu Krsna.