YO/Prabhupada 0529 - Loving Affairs of Radha and Krishna is Not Ordinary



Radhastami, Srimati Radharani's Appearance Day -- London, August 29, 1971

Egbiyanju lati mo nipa Krsna. Ti Krsna bafe gbadun iru igbadun wo lole se? Egbiyanju lati ni oye nipa oro yi. Alagbara ni Krsna, alagbara ni Olorun, gbogbo eyan lomo. Ti eni to lagbara ju ba fe gbadun iru igbadun wo lole se? Oye ko yewa. Rādhā-kṛṣṇa... Nitorina ni Svarūpa Dāmodara Gosvāmī se ko ese- iwe yi, rādhā-kṛṣṇa-praṇaya-vikṛtiḥ. Eto ife laarin Radha ati Krsna, eto aye yi ko, asimope ojo ta'ye yi na. Sugbon enikeni toba ni oye nipa Krsna avajānanti māṁ mūḍhāḥ (BG 9.11). Mudha, awo asiwere, ode wanrope eyan lasan ni Krsna je. Lesekese taba rowipe nkankanna ni Krsna je pelu wa... Mānuṣīṁ tanum āśritāṁ, paraṁ bhāvam ajānantaḥ. Awon asiwere wanyi, wan o mowipe paraṁ bhavam. wansi fe farawe rasa lila, ati Krsna lila. Awon asiwere wanyi po gan. Awon nkan bayi n'sele. Kosi oye nipa Krsna. Lati ni oye nipa Krsna si le gan.

manuṣyāṇāṁ sahasreṣu
kaścid yatati siddhaye
yatatām api siddhānāṁ
kaścin māṁ vetti tattvataḥ
(BG 7.3)

ninu aimoye eyan, boya ikan ninu wan a gbiynaju lati je ki aye re di mimo. Gbogbo eyan lon sise bi erank, kosejo pe afe k'aye se dara. Awon iwa eranko: ounje jije, orun, imo ako ati abo, ati ija.... gbogbo eyan lon sise bi awon erank nisin. Kosi ise i toni afi ti awon elede ati aja, lat'aro d'aale. "Ibo ni igbe wa? Ibo ni igbe wa?" lesekese toba ri igbe die, " nibo ni moti le ni asepo pelu okurin tabi obirin?" nibo ni moti le ni asepo pelu okurin tabi obirin?" Kosiyato laarin Iya ati aburo obirin.

Ile-aye elede niyen. ile-aye yi kon wa fun awujo elede.. awujo awon elede ni awujo aye isin, sugbon wanfe fipamo sinu aso ati aaso awoleke. agbudo gbiyanju lati ni oye. Lati mo nipa Krsna ni egbe imoye Krsna yi wafun. Sugbon agbudo sise, agbudo fojusile tab fe ni oye nipa Krsna. Tapasya brahmacāryeṇa śamena damena ca. Tapasya. Eyan gbudo se tapsya. Brahmacārya, aimobiirin. Tapasya. Lati fi ipari si imo ako ati abo tabi lati se ni iwonba die ni itumo Brahmacārya. Nitorina ni awujo Veda lati bere, lon ko awon omo-okurn lati di brahmacari, aimobiirin. Kodabi aye isin, ninu awon ile-iwe awon omo-okurin ati obirin ton ni odun mejila tin gbadun ara wan. Opolo wanti baaje. Kosi bonsele ni oye nipa awon nkan to gaju opolo wan ti sonu. laidi brahmacari, koseni tole ni oye nipa aye mimo. Tapasya brahmacāryeṇa śamena damena ca. Idari lori iye-ara wa ni itumo Sama, idari lori okan; damena, idari lori iye-ara, tyāgena; śaucena, mimo; tyāga, inu-rere nitumo tyāga awon ona lati mo nipa ara wa leleyi. Sugbon ninu aye tawayi o le gan lati monipa gbogbo awon ilana wanyi. Nioto-oro, kolese se, Nitorina ni Oluwa Caitanya, Krsna fun ara re, osi farare han pelu ilana kan:

harer nāma harer nāma harer nāmaiva kevalam
kalau nāsty eva nāsty eva nāsty eva gatir anyathā
(CC Adi 17.21)

Ile-aye Kali yuga... ni aye to kere ju ni sugbon awa si rope awa tini ilosiwaju gan ninu aye tawa yi. Nitoripe awon eyan dabi eranko. nitoripe awon eranko oni isemi ju ofin merin ara - ounje jije, orun, imo ako ati abo ati ija - Ni aye yi, awon eyan omoju awon nkan merin wanyi Kosi iroyin emi, awon eyan o si fe mo nipa emi Alebu ile-aye yi niyen. Sugbon ile-aye yi wa fun iwaadi nipa enitaje, " tani mi?" Kini ise-apinfunni ile aye-eda.