YO/Prabhupada 0528 - Radharani is Krishna's Pleasure Potency



Radhastami, Srimati Radharani's Appearance Day -- London, August 29, 1971

Eni ni ojo ifarahan Śrīmatī Rādhārāṇī, Rādhāṣṭamī. ojo medohun lehin ojo ibimo Krsna, Radharani farahan (isimi) Agbara itelorun ni Radharani je fun Krsna. Rādhā-kṛṣṇa-praṇaya-vikṛtir hlādinī-śaktiḥ. orisirisi agbara ni Olorun ni, wansi salaaye nipa re ninu awon Veda. Parāsya śaktir vividhaiva śruyate (CC Madhya 13.65, purport). Na tasya kāryaṁ karaṇaṁ ca vidyate. Olorun oni ise kankan tonse. Na tasya kāryam. Koni ise ton se. gege bi awon eyan pataki ninu aye yi, tabi awon olori ijoba, koni ise kankan ton se. nitoripe oni alabasepo ton sise fun, nitorina ni kose ni nkankan ton se. Gege na, Olorun fun ara re toni gbogbo agbara mefa, kilode toye ko se nkankan? Rara. Osi ni awon iranse to po. Sarvataḥ pāṇi-pādas tat. Ninu Bhagavad-gita: " Osi ni ese ati owo re nigbogb ibi." Ele ri Krsna, Koni ise kankan ton se. O kan gbadun ara re pelu awon gopi ati Radharani. Oun ko lon pa awon esu wanyi. Krsna ton pa awon esu, Vasudeva Kṛṣṇa niyen; Krsna gidi ko niyen. Krsna si le so ara re di pupo. Ara t'alakoko ton fesi ni Baladeva. lati Baladeva - Saṅkarṣaṇa, Pradyumna, Aniruddha, Vāsudeva. pelu irisi re bi Vasudeva lon sise ni Mathura ati Dvaraka. Sugbon Krsna ninu irisi alakoko re, Vrndavan lo wa ni gbogbo igba. Ikan ninu awon onkowe ni ilu Bengal, Bankimchandra Chatterjee, o se asise, pe Krsna towa ni Vrndavana, ati Krsna to wa ni Dvaraka ati Krsna to wa ni Mathura nkankanna loje. nkankanna ni Krsna je, sugbon osi le so ara re di pupo. Advaitam acyutam anādim ananta-rūpam ādyaṁ purāṇa-puruṣam (Bs. 5.33). Advaita. Although ananta-rūpam, ādyaṁ purāṇa-puruṣam, advaita. kosi'yato.

Krsna lelyi, toba fe gbadun, iru igbadun wo lole ni? Śrīla Jīva Gosvāmī ti salaaye. Paraṁ Brahman ni Kṛṣṇa je. Brahman, Paramātmā, lehin na Paraṁ Brahman. amuye meta ni otito to gaju ni. elomi le ri otito yi bi Brahman tioni irisi. awon jnani ton fe mo nipa otito yi, pelu ogbon ori wan, awon lon ri Otito to gaju yi bi Brahman tio ni irisi. awon ton si fe monipa Otitio togaju yi lati ona iṣaro, awon yogi niyen. awon lon ri otito yi bi Paramatma. Paramatma wa ninu okan gbogbo wa. Īśvaraḥ sarva-bhūtānāṁ hṛd-deśe 'rjuna tiṣṭhati (BG 18.61). amuye Paramatma leleyi. Aṇḍantara-sthaṁ paramānu-cayāntara-sthaṁ govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi. Ikan ninu awon irisi Krsna ni Paramatma yi je. Ninu Bhagavad gita wan sowipe athavā bahunaitena kiṁ jñātena tavārjuna ekāṁṣena viṣṭabhyāham. Ekāṁṣena. Nigbati Arjuna ati Krsna femo nipa gbogbo awon amuye Krsna, Osi salaaye ninu Ese-iwe mejila (mewa), nkan bayi bayi nimi. Laarin awon bayi.,..bayi nimi.. Ni ipari osi sowipe " So si fe kin tesiwaju si ? Kan gbiyanju lati mowipe pelu agbara kekere ara mi, mole wole sinu agbaye yi, nkan ton fun agboye iseda yi laaye niyen". Ekāṁṣena sthito jagat (BG 10.42). Jagat. Lori ikan ninu awon apa kekere Krsna ni gbogbo agbaye yi wa. ti Kṛṣṇa bawole aṇḍāntara-sthaṁ paramānu-cayāntara-stham, Gbogbo agbaye yi o le wa laaye to baje wipe Krsna o wonu e. Gege bi ara, kosi bosele wa laaye laisi emi ninu e. lesekese ti emi na ba jade, ara na o ni iwulo mo. Koba je ara alakoso ijọba ni ile aṣofin , lesekese ti emi na ba jade, ara na o le ni iwulo kankan mo. Gege na nitoripe Krsna wole sinu agbaye yi ile-aye yi seni iwulo na Bibeko, iyepe lasan loje; kowulo. Ekāṁṣena sthito jagat.